Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán Ìlú Abeokuta nígbà tí a wò ó láti orí òkè olúmo (olumo rock).

Àwòrán Ìlú Abeokuta nígbà tí a wò ó láti orí òkè olúmo (olumo rock).

Òkè olúmo jé òkè kan gbòógì tí a kò le fi owó ró séyìn nínú àwon òkè tí n be ní orílè èdè Nìjíríà, kìí wá se orílè èdè yí nìkan ni a kò tile fi owó ro séyìn bí kò se wípé káàkiri ilè Adúláwò.
Orí òkè yí ni àwon kan wà tí won sì ti ya àwòrán ilú kan ní ilè Yorùbà, tí ó sì je wípé Yorùbá ni won ñ so níbè àti wípé omo Yorùbá àtàtà ni wón. Orúko ìlú náà a máa jé Abeokuta. Abeokuta ni òkè olúmo wà bóyà torí okè yíì ni won ti so orúko náà, ta ló mò? nítorí àwòrán náà fi hàn wípé abé òkè ímyí ni ìlú náà wà.
Òkè olúmo wà ní ìlú Abeokuta, ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won sì ti rin ìrìnàjò lo síbè láti lo wo àwon àrà méèrírí tí ó wà lórí òkè yí.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti