Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.

Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.

Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.
Omo egbé oní ìgbálè tí won fà kalè láti lo fún Gómìnà, egbé tí a mò sí APC ti yan Gboyega Oyetola láti lo fún gómìnà ìpínlè Osun.
Àjo tí ó n sètò ìdìbò ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbá orókè níbi idìbò tí won sèsè tún dì tán.
APC rí àwon olùdìbò tí ó tó 255,505, tí àwon PDP sì ní èèyàn tí ó tó 255,023…

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

A list of prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 10,000)

A list of prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 10,000)

To understand the Yoruba language, common vocabulary is among the important sections. Common Vocabulary contains common words that individuals can use within daily life. Numbers are one section of common words found in daily life. If you’re interested to master Yoruba numbers, this post can help you to master all numbers in the Yoruba language using their pronunciation in English. Yoruba numbers are found in day-to-day life, so it’s essential to master Yoruba numbers. The below table provides the translation ...