Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán okò Mercedes Benz tí Obafemi Awolowo fi se ìponlogo ní ìgbà tí ó fé lo fún Ààre orílè èdè Nàíjíríà.

Àwòrán okò Mercedes Benz tí Obafemi Awolowo fi se ìponlogo ní ìgbà tí ó fé lo fún Ààre orílè èdè Nàíjíríà.

Obafemi Awolowo tí ó jé ògbóntarìgì àti adarí àwon olósèlú, tí ó sì kó iPa takuntakun láti jé kí orílè èdè yí di olómìnira.
Làra àwon ohun tí ó wà ní ibi tí won kó nkan ìsèńbáyé sí tí a mò sí Museum, ni okò tí a mò sí Mercedes 230:6.
Okò yí ni Awolowo lò láti fi se ìponlogo àti láti fi rin gbogbo ìrìn àjò ní odùn 1979 àti 1983, tí okò náà jé ríra ní odún 1970….

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Deborah Samuel

Why are Nigerian celebrities keeping quiet over Deborah Samuel’s gruesome murder

I remember when George Floyd was killed in America by white police officers, Nigerians protested in Abuja and Lagos. I’m not saying that was bad though, he was a black man like me. But here is my grouse, Africans, and Nigerians, in particular, are always quick to show support when something happens elsewhere, but they will not do anything when it comes to fellow Nigerians. By now, there should be massive protests across the country demanding justice, but none of ...