Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .

Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .

Àwòrán ògbó-n-ta-rì-gì olórin ní orílè èdè Nàíjíríà, Fela Anikulapo kuti àti agbejórò rè. Gbajúgbajà agbejórò tí ó tún jé bàbá ìlúmòóká olórin Falz d bahdguy ògbéni Femi Falana àti bàbá Beko Ransom Kuti .

Mo gbàgbó wípé òrò ilé-ejó ni àwon akoni yí nso, àbí béè kó ni.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti