Ogún-l’ógbòn àwon eléré orí ìtàgé ni ó n fi tipátipá béèrè ìbálòpò lówó àwon èèyàn láti le jékí won hàn nínú eré ti orílè èdè Nàíjíríà (Nollywood) gégé bí ìyá kan àti eni tí ìsèlè yí selè sí se fi èsùn kan olùdarí eré Fabiyi.
Classes of Egbe (Heavenly Mate of Every Human) Also known as Alaragbo in some areas of Yoruba land, Egbe is generally more associated with children than with adults according to Eji-Ogbe. Based on the character traits of human on Earth, the Yoruba have classified Egbe into different categories. Ìyálóde Ìyálóde is regarded as the leader of Egbe on Earth. Leadership quality is most evident characteristic of this class of Egbe. Going by the name, it may appear that only females ...