Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. 
Àwon Agbófinró

Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. 

Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun míràn tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. Ní ìsàlè ni òrò tí agbenuso àwon Agbófinró ìpínlè Èkó, SP Dolapo Badmos so.
“E jò ó tí enikéni bá fi káàdì ìpè ráńsé sí yín tí eni na sì pè padà wípé àsìse ni pé kí E fi ráńsé padà sí àwon. Tí o bá fi ráńsé padà, wón sì máa pè yín láti bèèrè sàpéjùwé yín wípé àwon fé dúpé lówó yín fún ohun tí e se àti wípé àwon fé gbàdúrà fún yín E má dá won lóhùn E má sàpéjùwé ara yín ooo. Ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà láti gbé ènìyàn nìkan.
E jò ó ejé kí á máa fura kí á sì sóra nínú gbogbo ohun tí a ń se lójoómó kí á ma ba bó sòwó….

 

Continue after the page break for English Translation.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti