Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà
waec

Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà

Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà (#525k) fún níní àmì “A” mésàn-án (9A1) nínú èsì ìdánwò àsekágbá girama.

Rántí Cynthia Chinecherem, Arábìnrin tí ó ní àmì “A” nínú gbogbo isé tí ó se nínú ìdánwò àsekágbá girama (WASSCE) tí won sèsè se tán, àwon ènìyàn rere Nàìjíríà ti dìde láti ki kú isé.

Chinecherem ní àmì “A1” nínú gbogbo isé mésàn-án tí ó se, ó sì tàn káàkiri èro ayára-bí-àsá (Twitter) nígbà tí ò ń lò èro ayára-bí-àsá @Dr. Damages fún èsì ìdánwò náà ní ojó kokànlélógún osù keje.

Ò n lò èro ayára-bí-àsá míràn, @Chydee nígbà tí inú rè dùn ó ri dájú wípé omobìnrin tó yege jù lo ní èrè fún isé àsekára yí! Àti ìròyìn Ìsèlè ìgbèyìn ni wípé wón máa fún -un ní #525,500: wo àwòrán ní ìsàlè…

Continue after the page break for English Version

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti