Home / Art / Àṣà Oòduà / Olùkó kan ní Benue ni won ní kí ó San mílíònù kan àti ààbò Náírà (₦1.5m) fún owó orí.
ben

Olùkó kan ní Benue ni won ní kí ó San mílíònù kan àti ààbò Náírà (₦1.5m) fún owó orí.

Arákùnrin tí ó sèsè parí èkó, tí ó sì ń sisé olùkó ní ilé-ìwé aládàáni girama kan tí ó fé fé ìyàwó ní àwùjo kan ní Zone “A” ní ilè Tiv ní ìpínlè Benue, ni won ti fún ní àwon ohun tí yóò rà tí àpapò rè jé mílíònù kan àti ààbò náírà (1.5m) fún owó orí ìyàwó àfésónà rè.

Àwon nkan pépèpé míràn sì wà tí yóò tún San owó fún bíi :Ìgbéyàwó ìbílè (Traditional wedding) àti ti ìgbéyàwó ilé ìjosìn (church wedding).

Gégé bí oòduà rere se so, akékòó sì ni ìyàwó náà.

Eléyìí ò wa pò bí ….
Continue after the page break for English Version

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo15102024

#Masoyinbo Episode Sixty-Five: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture.