Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón lólè ní Bayelsa.

Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón lólè ní Bayelsa.

Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán.
Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó bíi Ìbon, òbe, àkéé lówó, tí won fi lo ká arábìnrin tí a mò sí Jane nílé pèlú àwon míràn náà.
A gbo wípé owó tí àwon olè yí jí lo kò ní ònkà pèlú àwon nkan míràn náà nígbà tí won wolé síwon lára tán, won wolé siwon lára láti ojú fèrèsì.
A gbo wípé àwon adigunjalè yí lo láì sí eni kankan láti yèwón lówó wò. Àti wípé won kò pa enikéni bí kò se wípé won fi àpá sí àwon kan lára.
Àwon ará àdúgbò n bèrè fún àbò tí ó péye láti gbawón lówó irú ìsèlè náà.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Happy New Calendar Year!!! It is 10068 of the Oodua Yoruba Calendar-–-KỌ́JỌ́DÁ

The Yoruba traditional calendar, called Kọ́jọ́dá, starts the new year on June 3rd and ends on June 2nd the following year. It’s a lunar calendar with a 4-day week (each day honoring different Orisa), 7 weeks in a month, and 13 months in a year—so their year is 364 days long. The months and weeks are deeply tied to farming cycles, moon phases, and religious rituals.The traditional Yoruba week has four days. The four days that are dedicated to the ...