Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
afurasí

Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.

Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi Awolowo, kí á tó dé ilé-ìwé Government Technical College Ikorodu, pèlú àdá àti àpò tí ó kún fún ègbin.

Nígbà tí won lo ba tí won sì bèèrè àwon ìbéèrè kan lówó rè, èsì rè kò dáńgájíá, kò le sàlàyé ara rè, ó so wípé àgbè ni òun àti wípé àwon ebí òun ti kú. Àwon àgbà àdúgbò náà kò jé kí àwon òdó dá sèríyà fun láti owó won, wón ri wípé wón fà á lé aeon olóòpá ní ilé-isé olóòpá Igbogbo lówó, níbi tí won ti ń fi òrò wa lénu wò……

Cntinue after the page break fro English Translation

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti