Home / Art / Àṣà Oòduà / Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.

Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.

Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.
Tokotayà tuntun, Banky W àti Adesua Etomi pèlú ègbón Adesua Etomi okùnrin, ìyá rè àti àwon òbí oko ní apá òtún èyí ma tún dára Ooo.
Àwon òbí tí inú won n dùn náà kò yunra láti bá àwon omo won yà àwòrán.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

komi n yooba

Kọ́mi n’Yoòbá || episode 5 || This is the funniest episode ever..