Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se eré pèlú J Cole àti wizkid.
Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn ẹlẹsin meji ti o ku(Kitẹẹni ati Musulumi).Wayi o, igbakeji alaga fun ẹgbẹ agbaagba nilu Isẹyin, Alhaji Bọlaji Kareem, ti kede pe ija ti dopin, ogun si ti tan lori aawọ ọrọ sise nilu Isẹyin.Kareem, ẹni to soju ...