Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè. Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí owó, orò bàbá rè má sisé mó, tí ó je wípé takuntakun ni ó fí n sisé láti le di èèyàn ñlá àti èèyàn pàtàkì tí àlá rè sì ti wá sí ìmúse. Omo bàbá olówó ni gbogbo ayé mo Davido sí nítori omo ìdílé Adeleke láti Ede ni. Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè Nìjíríà báyìí. Sé owo ló tún fé ni àbí kíni? sùgbón ìfé orílè èdè rè tí ó wà lókàn rè ní ó mu fé sin orílè èdè rè.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


