Home / Art / Àṣà Oòduà / Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà. 

Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà. 

Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye láti ilé ìgbìmò asòfin àgbà. Nígbà tí ìròyìn náà wá, Dino gbe lo sí orí èro ayélujàra rè (facebook) láti so wípé nkankan kò le se òun àti wípé àwon tí ó gbé ìgbésè náà setán láti s’èwòn .
Ní òwúrò yí, ó tún gbe lo sí èro ayára-bí-àsá (twitter) láti wo ìsesí míràn lórí rè….

English Translation
Continue after te page break

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.