Home / Art / Àṣà Oòduà / E gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,
asa yoruba

E gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,

E jiire eyin eeyan mi, e je ki a gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila, mo nki lati inu Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ), o ki bayi pe,’ Bibi inu ko da nkan, suuru ni baba Iwa, agba to ni suuru, ohun gbogbo lo ni,a difa fun Orunmila lojo ti baba maa nire gbogbo, Ifa ni mo gbowo o, mo gbomo, mo gbaiku, mo gba suuru. Igba ti baba ni suuru lo nire gbogbo, lo jogun aye.

Ese ifa yii gbawa niyanju pe ti a ba le rubo taa si ni suuru, ire gbogbo ni yoo to wa lowo. Ki Olodumare ma sai fun wa lemi suuru ti a o fi rire wa gba, inu buruku ko nii biwa si oloore wa, apari inu wa ko ni ba tode wa je, (Aase. )

Good morning my people, let us all hear from Olodumare through the sacred Odu of Orunmila, I’m quoting from Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ) it reads thus,’ Anger leave one with no profit, calmness is the best of attitude, any elder that possesses calmness has everything, they made divination for Orunmila, the day he would possess every goodness, Ifa said, I accept money, I accept children, I accept long life, I accept gentility. It was when Orunmila became patient he had every goodness and inherited the whole world. This sacred odu is advising us that if we make appropriate sacrifice and be patient, every good things shall come our way.

May Olodumare grant us the spirit of patience, so that we shall possess our good possession, may we not be annoyed with our benefactors, may our inner head (luck ) never cause a negative effect on the outer head (intellect ). (Aase )

Abayomi Fadeyi

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti