
Joke silva pín èrò rè ní orí èro ayélujára, ó ko síbè wípé
“E má se jé kí èro ayélujára tàn yín je. Òtító tó dájú ni wípé kìí se isé eré orí ìtàgé nìkan àwon tí e rí ni orí èro ayélujára ni n se, bíkòse wípé òpò ni ó ni nkan míràn tí won n se tí won fi n rí owó se ilé ayé won.òtítò tí ó wà níbè ni wípé, kò sí owó ní orílè èdè yí fún ilé ìsé wa atiwípé kò sí orò ajé ní orílè èdè Nìjíríà”.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

