Home / Art / Àṣà Oòduà / Èèmò! Nígbà tí Gómìnà ìjòba ìpínlè Oyo wó ilé ìròyìn Yinka Ayefele ní ìlú Ibadan. Èyí kìí se àheso rárá, béè ní Gómìnà ìpínlè Oyo kò bá Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yinka Ayefele se eré rárá.

Èèmò! Nígbà tí Gómìnà ìjòba ìpínlè Oyo wó ilé ìròyìn Yinka Ayefele ní ìlú Ibadan. Èyí kìí se àheso rárá, béè ní Gómìnà ìpínlè Oyo kò bá Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yinka Ayefele se eré rárá.

Ní òwúrò ànà tí se ojó Àìkú ní ariwo ta ní ìlú Ibadan ní ìpínlè Oyo nígbà tí ijoba ìpínlè náà pàse kí won wó ilé-isé ìròyìn ti Yinka Ayefele tí a mò sí Fresh Fm tí ó wà ní òpópónà Challenge ní ìlú Ibadan.

Ilé-isé ìròyìn yí won ní ó won mílíónú lónà 800. Èyí kò da ní gbogbo ará ìlú ñ pariwo nítórí wípé Yinka ko le dìde rin.
Gégé bí a se gbó àwon omo orílè èdè Nìjíríà ti bèrè síní ran-án lówó tí òpò sì ti ñ dá owó fun.
Kí olúwa bá wa se é ní ilé oba tó jó ewà ló bùnkùn.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti