Ni Àná tí ó jé ogbòn-ojó osù keje odún 2018, ni eka-èkó ìmò àti Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò.
Òjògbón Wole Soyinka kò gbéyìn rárá Baba náà péjú pésè níbi odún náà.
Àsèyí se àmódún. (Àse).
Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...