Home / Art / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti

Gbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti

Gbajúgbajà a gbé òrò sórí aféfé ti gbe sí orí èro ayélujára tí a mò sí insitagiramu, láti jé kí gbogbo àgbáyé mò wípé òun ti bímo, nígbà tí ô ya àwòrán n’ílé ìwòsàn, tí ó sì pe omo máà ní Baby J.

Ó ko síbè wípé…
Òlúwa, èmi náà ti di ìyà, Baby J ti dé! Mo bímo ní ojó ketàdínlógún, eléyìí wuyì púpò. Modúpé púpò èyin èèyàn mi fún àtìleyìn yín fún ìrìnàjo náà. Mo ní’ìfé yín.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti