Home / Art / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà òsèré Olu Jacob mò wípé àgbàtó omo ni mí báyìí ni Joke Silver se so.

Gbajúgbajà òsèré Olu Jacob mò wípé àgbàtó omo ni mí báyìí ni Joke Silver se so.

Gbajúgbajà òsèré, Joke Silver so wípé nse ni olóògbé E.A Silver àti Dr.Abimbola Silver gba òun tó ni sùgbón nse ni kìí se wípé òun kò mò télè .
Joke Silver so wípé nígbà tí ó yá ni oko òun mò wípé won gba òun tó ni.
Bí ó tilè jé wípé won gba mama tó ni baba kò saláì má n’ífè rè béè.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn ẹlẹsin meji ti o ku(Kitẹẹni ati Musulumi).Wayi o, igbakeji alaga fun ẹgbẹ agbaagba nilu Isẹyin, Alhaji Bọlaji Kareem, ti kede pe ija ti dopin, ogun si ti tan lori aawọ ọrọ sise nilu Isẹyin.Kareem, ẹni to soju ...