Home / Art / Àṣà Oòduà / Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Gómìná ti ìpínlè Anambra tuntun, Gómìnà Willie Obiano ní ojó etì (Friday ) ti lo kí Ààre Muhammadu Buhari ní ilé-ìjoba ní ìlú Abuja.
Obiano ti dúpé lówó Buhari nítorí kò se àgàbà-n-gebè níbi ètò ìdìbò tí ó kojá ní Anambra.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti