Home / Art / Àṣà Oòduà / Gomina ipinle Kwara ti da Jelili oniso lola
Femi Adebayo

Gomina ipinle Kwara ti da Jelili oniso lola

*Femi Adebayo n wonu oselu lo diedie

Nibayii, gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed, ti yan ogbontarigi onisetiata, Femi Adebayo, gege bi oluranlowo pataki nipa ise ona, asa ati irinajo-afe (Special Assistant on Arts, Culture and Tourism). Osere ti inagije re tun je Jelili ko le pa ayo naa mora pelu bo se kede iyansipo re naa lori ayelujara fun awon ololufe re pata.

Bakan naa lo tun un dupe lowo gomina ipinle Kwara fun anfaani ti won fun un lati kopa ninu idagbasoke ipinle Kwara. Igbese tuntun yii ni awon kan ri gege bi ategun fun osere naa lati ridi joko ninu oselu ipinle re. Eleyii ti won lo se e se ko fun ni koriya lati gbe apoti idibo ninu eto idibo ojo iwaju.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

femi

Femi Adebayo Salami spotted with Ini Edo & Lai Mohammed (Photo)

Oga Bello’s son Femi Adebayo Salamis hared the photo above on his instagram page and caption “Still @ the National Summit on Culture and Tourism with my pretty @iniedo , Minister for Information Alh Lai Mohammed”