Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó tó di wípé ó di Ààre ó ti kókó sìnlú gégé bíi Igbákejì Ààre orílè èdè yí ní odún 2007 di 2010 àti gégé bíi Gómìnà Ìpínlè Bayelsa láti odún 2005 di odún 2007.
Ó pàdánù ìdíjé fún Ààre orílè èdè Nìjíríà ní odún 2015 tí Ààre Muhammad Buhari sì gbégbá orókè, òun ni Ààre àkókó tí ó wà lórì oyè tí ó sì tún pàdánù ìbò.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

