Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn
ife

Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé,
Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé,
Ìràwò òwúrò tèmi nìkan,
Olólùfẹ́ mi,
Nínú aba ayé yìí
Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ,
Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi
Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon,
Ife ìwọ olólùfẹ́ gbokan mi,
Ìwo ni nkan rere ti o sele sì,
Mo mọ ẹ ìmò mi lékún,
Mo mọ ẹ ó jẹ kí mọ àǹfààní ohun tí ẹdua fún tí mo fi lè ṣe ọmọ aráyé lore…

Mo nife re…

Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

http://edeyorubatiorewa.blogspot.co.uk/2016/08/ife.html

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti