Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìfé Mi (My Love)

Ìfé Mi (My Love)

Ìfé Mi (My Love)

Eni bíi okàn mi
Adúmáradán orenté
Olólùfé mi àtàtà
Ìfé re ní n pa mí bí otí òyìnbó
Lá ì gbó ohùn re
Mi ò lè sùn mi ò lè wo
Léyìn re kò sí e lò míràn
Mo wo òtún mo wo òsì
Mo wo iwájú mo wo èyìn
Mi ò rí arewà omoge
Tó ní’wà bíi ìwo
Iwájú ù re
À wò da tó ní enu bíi òdòyò
Èyìn re
À wò ká’wó mó rí kó sí kòtò
Bí o bá sá’ré whàálà
Bí o bá rora rìn ìjòngbòn
Ìwo ni mo fé
Ìwo ni okàn mi yàn
Mo máa ní ìfé è re tí tí di ojó ikú mi ni
Olólùfé mi
Mo ní ìfé re
Nítorí ìwo ni ÌFÉ MI.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti