Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà.
Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ní kíákíá kí ò sì dá gbogbo owó àláwánsì tí ó gbà fún Àádòrún ojó padà.
Nígbà tí ó sì wà ní ipò, ilé ejó gíga ti kéde Shuaibu Lau gégé bí asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà ti àríwá Taraba. Àse náà kún fún ìdájó tí ó wà nínú fáìlì ilé-ejó kò témi lórùn láti owó Shuaibu Lau, ó ta ko ìpinnu ilé-ejó kò té mi lórùn nígbà tí ó jáwé olúborí tí won sì gbe fún elòmíràn ní ònà tí kò tó.
Ile ejó tún pàse fún ètò ìdìbò (INEC) láti se ìwé-èrí tuntun fún ìpadàbò Lau.
Ilé-ejó gíga jù tó ri to ìpinnu àwon omo egbé tóronú márùn-ún tí ó wáyé wípé “olugbèjà ara rè ní ètó láti kópa gégé bi àwon tó kùn náà se létòó ní ìbèrè ó rò wípé wón yan òun je ni .ó ní ètó láti lo sí ilé-ejó .
Eni tí won fi ró pò rè ní ìbèrè pèpè ti ìbò rè se òfò nígbà tí ó jé wípé olugbèjà ara rè ló gbégbá orókè nínú ìdìbò náà. Ohun tí ó kùn ni wípé kí won kéde wípé olugbèjà ara rè ló gbégbá orókè ní ìbèrè pèpè.. …
Continue after the page break for English translation.