Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.

Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.

Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè .
Gboyega Oyetola ni ó dúró fún egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC; Ademola Adeleke, ni ó dúró fún egbé tí a mò sí PDP, egbé alábúradà tí Iyiola Omisore sí dúró fún egbé Elésìn tí a mò sí SDP.
Ìpínlè Òsun ó dowó yín ooo, èyin omolúàbí e ronú ó.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti