Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.

Ìsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.

Gégé bí Holychidi Ojlkorie, ìgbákejì olùgba oko àti aya n’ímòràn ti ìjoba ní ìpínlè Imo télè, òpò ènìyàn bí ogbòn ni won kú níbi ìjàmbá burúkú tí ó selè láìpé láàrin glokò epo petiróòlù àti okò èrò elérò méjìdínlógún (18) ni won ti sin wón papò.
Ó ko síbè wípé .
” ìsìnkú òpò, ìsìnkú àwon tí wón kú sí inú ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo . Won jóná ju bí ó ti ye lo. Kí olúwa té won sí aféfé rere.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti