E MAA WI TELE MI :
……..
*Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je.
*Atije-atimu mi ko ni nira.
*Oluwa so egan mi dogo.
*Aye ko ni ta epo s’aso ala mi.
*Fitila ogo mi ko ni ku.
*Aso iyi mi koni faya.
*Olorun ye iku ojiji kuro lori mi.
*Oluwa ma je ki n se ise ti N ko ni duro je(Ase).
Fun ipolowo oja lorii Radio/TV tabi MC : +2347031174331.
`Aare Olasunkanmi Alani Agbasaga
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

