Home / Art / Àṣà Oòduà / Iwure Owuro Toni 04-05-2016
orunmila baba ifa

Iwure Owuro Toni 04-05-2016

E MAA WI TELE MI :
………
*Owo ko ni ri mi sa.
*Oju owo ko ni pon mi.
*Ojo ibukun mi ko ni di ojo abuku.
*Alaaanu mi ko ni ko’yin si mi.
*Edumare ma je ki n teni ti ika eda
*Ayanmo mi ko ni di yanmoyanmo(Ase).
……….
E ku ojulona IBILE FESTIVAL SEASON1.
……….
Ilu ibile.
Ijo ibile.
Orin ibile (Ewi, Ijaala, Esa).
Iwosan ibile.
Ounje ibile.
Aso ibile.
‪#‎IBILE2016‬
……..
Fun ekunrere alaye : +2347031174331

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

aje

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni Aje dakun wa jo koo temi ki or ma kuro mud my Translation Continue after the page break