Home / Art / Àṣà Oòduà / John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta. 
Olúfà python

John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta. 

 Konmísónà tí ó ń mójú tó àyíká (commissioner of environment), tí a mò sí Hon. Barr John Nani àti àwon emèwà rè kolu tí won sì pa olúfà ńlá tí ó won òsùwòn tí ó tó mítà lónà mérin ó dín mérin (3.6m) ní Awai nígbà tí won gbìyànjú àti sín kànáà (canal) láti gbógun ti omíyalé..

Continue after the page break for English Version
Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event

Live Event Video: The Coronation of The 21st Olu of Warri

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event