Home / Art / Àṣà Oòduà / Kini yoo sele si orekelewa aya Abubarka Audu?

Kini yoo sele si orekelewa aya Abubarka Audu?

Omodebirin yii ni okan ninu awon iyawo tuntun ti Abubarka Audu ko sile to fi n sararindin nigba aye re.

Gege bi ohun ti Olayemi Oniroyin gbo, ojo ori omobirin naa ko le ju bi odun mejidinlogun (18) si ogun odun (20) lo.

Nibayii ti baba olowo eni odun mejidinlaadorin (68) ti wa ku lairo tele yii, kini yoo sele si orekelewa aya re?

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

yoruba

Can we speak Yoruba language without code mixing? is it important?