Home / Art / Àṣà Oòduà / Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.

Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.

Arákùnrin kan ní orílè èdè Nìjíríà ti ya òpò èyan lénu látàrí sése ìgbéyàwó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar rè. Tí e bá rò wípé e ti ri tán , eléyìí tún ya ni lénu ò.
Harri best ti pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí Insítágírámú láti pín àwòrán òun àti guitar rè tí won sì múra bíi toko taya, nígbà tí ó ko ìfé tí ó ní sì orin.
Ìsèlè yí selè ní ìpínlè Èkó, nígbà tí ó sì n ya èèyan ní enu wípé se iró ni àbí òtító.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti