Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole

Obara Irete

I I
I II
II II
I II
ObaraIrete

Ponusesere Awo Ile Agbonniregun
O difa fun Agbonniregun Oloja Oribojo
Nijo ti won ji
Ti won n foribale fun Ikin won
Eni ba foribale a jogbo
Eni ba foribale a jato
Eni ba foribale laa ni ire gbogbo
Abere nii fi tojutimu sise
O difa fun foribale ki o rire
Awa wa foribale a o ku mo
ObaraRete, Ori a gbo ke!
Ifa Ori mi re o!
Mo fori bale!
Ifa o jiire loni ooooo!

`Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifa on sex

Ifa on Sex and Sex Positions With Owomide Ifagbenusola