Home / News From Nigeria / Breaking News / Odómokùnrin odún mókàndílógún (19years) tí ósì jí olóyè kan gbé ni owó tè ní ìpínlè River.

Odómokùnrin odún mókàndílógún (19years) tí ósì jí olóyè kan gbé ni owó tè ní ìpínlè River.

Àwon òlùgbógunti Adigunjalè ti ìpín Okehi ní ìpínlè River ni owó won te òdómokùnrin kan tí ó ń jé Emeka Nwala tí ó jé odún méèdógbòn (25years) àti òdómokùnrin Otamasiri Onyesu tí ó jé odún mókàndílógún. Tí won sì fi èsùn kan wón wípé àwon ni won jí olóyè pàtàkì kan gbé ní ìlú Umuehem tí won jí gbé pa mó fún òpòlopò ojó.
Àwon ìgbìmò oníwà rere ìlú ni ó s’ètò bí won se rí won mú nípa gbígbá rùkù ti àwon olóòpá púpò. Won ń ran àwon olóòpá lówó láti gbé won lo sí ilé-ejó láìpé…

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Deborah Samuel

Why are Nigerian celebrities keeping quiet over Deborah Samuel’s gruesome murder

I remember when George Floyd was killed in America by white police officers, Nigerians protested in Abuja and Lagos. I’m not saying that was bad though, he was a black man like me. But here is my grouse, Africans, and Nigerians, in particular, are always quick to show support when something happens elsewhere, but they will not do anything when it comes to fellow Nigerians. By now, there should be massive protests across the country demanding justice, but none of ...