Bóyá láti jé kí àwon òré rè lórí èro ayélujára(Facebook) tèka wípé àwon féràn rè ni tàbí kí ó fi di gbajúgbajà. Òdókùnrin tí kò dàgbà jù, tí ó sì jé ò n lò èro ayélujára(Facebook), tí a mò sí Samuel Sammy-g ni ó ya àwòrán báyìí tí ó ko “666”sí iwájú orí rè .