Home / Art / Àṣà Oòduà / Òdómokùnrin odún mókàndílógún (19 years) fé odómobìnrin odún méèdógún (15 years) ní ilè àríwá (North) ní orílè èdè Nàìjíríà.
arewa

Òdómokùnrin odún mókàndílógún (19 years) fé odómobìnrin odún méèdógún (15 years) ní ilè àríwá (North) ní orílè èdè Nàìjíríà.

Àwòrán tí ó gba aféfé ni ti àwon tokotayà yí tí oko jé odún mókàndílógún tí ìyàwó sì jé odún méèdógún ní ilè àríwá orílè èdè Nàìjíríà.
Ò n lò èro ayélujàra kan ni ó pín àwòrán tokotayà yí, tí ó sì kí won kú oríre…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete