Home / Art / Àṣà Oòduà / Odun Thaipuisam: Irin sonso ni awon eniyan fi n gun ara won niluu India
india

Odun Thaipuisam: Irin sonso ni awon eniyan fi n gun ara won niluu India

Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. Igbagbo won ni wi pe, bi inira won ba se po to nipa fifi irin sonson gun ibikibi lara won, bee naa ni ibukun won yoo se po to.  Odun Thaipuisam ti di gbajugbaja ni ilu India, atokunrin atobirin ni won si n pejo nibi odun yii lati gba ibukun nla.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti