Ohun méje (7) tí ó jé èdùn okàn tí enikéni kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga.
1- ilé-èkó gíga ifáfitì wà fún mímo irú èèyàn tí o jé, lo àkókò àti ànfààní tí o bá ní dáadáa, láti mo ìlépa re tí ó jé wípé nígbà tí o bá se tán o kò ní fi àkókò re s’òfò.
2- ní ìlépa tó dáńgájíá.
3- tí o bá ní èbùn tàbí ohun tí o féràn láti ma se má fi àkókò s’òfò láti sin enikéni! Lépa ònà tìre.
4 – má jè é kí enikéni so fún o wípé “o kò le se é”.
5- Gbìn sínú okàn re má sì jé kí okàn re rè sí isé òòjó re : èkó lórí ara eni (self study), èkó àgbà (post grad study), isé re (courses), eré ìdárayá (sport), kíka ìwé (reading) Àpérò (seminar) ìrìnàjò (travelling), èdè (linguistic).
6- má gbé okàn lé ònà àtije kan, gbìyànjú láti ní ònà míràn.
7- tí o bá pinnu láti sisé l’ábé enikéni ó ye kí o mò wípé ìgbéga re ó dá lórí òsùwòn 40% fún isé kára kára àti 60% òsèlú tí ó sì jé wípé kò ní sú e….
Continue after the page break for English Version