Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU).
Ìsèlè burúkú gbáà ní Óní selè ní ojó kewàá osù keje odún 1999 ní ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university nígbà tí èmi oní inú ire sì gba ibè lo.
Afrika se béè Ó ta èjè rè sílè fún àwon akékòó ilé-èkó yí láti dènà egbé òkùnkùn láti ìgbà náà ni àláfíà, ìfòkànbalè ti wà nínú ogbà yí. Njé ó wá ye kí á gbàgbé ojó yí bí?
Èní lópé odún mókàndínlógún tí Afrika kú fún wa, kí ló wá dé tí a kò le polongo “kí egbé òkùnkùn wá sí òpin ” kí lódé tí a kò le rántí èjè tí Óní kú fún akékòó?
Akoni ni Afrika ejé kí á se ayeye ìrántí fun, kí á kí àwon ebí rè wípé wón kú afárárekù eni rere..
Njé Ìwo tí setán láti gbógun ti egbé òkùnkùn bí?.