Home / Art / Àṣà Oòduà / Oko mi ati iya re loba aye mi je
Relationship

Oko mi ati iya re loba aye mi je

Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re)

Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA N TOJU RE . O so wipe rara , ko toju oun

Haaa . Mo ni iwa buruku ni oko ati iya re hu . Sugbon nigbati mo beere oro siwaju si , mio mo nkan ti molee so mo

Mo beere wipe iru ise wo ni oko nse bayi ati wipe ile melo loti ko .
Iyawo yi so wipe oko oun koi ti ni ise lowo , o si n wa ise ni . Koi ti ko ile , room and parlor ni awon gbe ,. Awon si je owo ile odun .

Eyin eeyan mi , ejowo se won gba kadara iyawo yi fun oko re nitooto ?
Bcos , iyawo tenumo wipe won gba arisiki oun fun oko , sugbon ko lee wulo fun

E jowo e bawa dasi oro , ko ye emi rara
e seun oooo

LoBaTaN

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti