Gégé bí ò n lò èro ayélujára tí ó gbé ní Yola tí ó pín ìròyìn ìsèlè yí se so, olópàá tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí ní won yà nígbà tí ó n GBA owó èyin lówó àwon dérébà.
Bí ó bá wá di òla e ma ri àwon olópàá tí won a ma pariwo ” àyípadà bèrè láti òdò àwon”…
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

