Home / Art / Àṣà Oòduà / Omo odun metadinlogun (17) joba nile Naijiria
Ubulu

Omo odun metadinlogun (17) joba nile Naijiria

*Isele naa farape ti Awujale tile Ijebu

Oba Sikiru Adetona, Awujale tile Ijebu, eni ti won bi lojo kewaa osu karun-un odun 1934 gori ite awon baba re lojo keji osu kerin odun 1960 leni odun merindinlogbon (26), eleyii ti n se eni ojo ori re kere julo lati joba nile Yoruba.

Nibayii, Obi Chukwuka Noah Akaeze I, eni odun metadinlogun (17) ti gori ite awon babanla baba re gege bi eni ojo ori re kere ju lo lati joba ni gbogbo ile Naijiria.

Obi ni won pe wale lati ile Biritiko nibi to ti n kawe lowo lati wa joba le awon eniyan Ubulu-Uku to wa ni ipinle Delta lori. Eleyii lo waye leyin ti awon ajinigbe kan seku pa baba re to je oba tele ni ibere osu kinni odun taa wa ye.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti