Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà bí o bá gbìyànjú tí a kò rí irú rè rí, o kò leè yí enikéni padà ní ayé yìí. Àsàyàn kan péré tí o ní ni kí ènìyàn mo ìwà fún oníwà. Onítìjú obìnrin àti aláròyé okùnrin le gbé papò láìsí ìjà. Níbi tí a bá ti gbó ara eni yé ni ìfé máa ń gbé. Àwon ònà rè tí a le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin.
Ònà tí a le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin rè é.
1 . Ó fé dáwà : tí ó bá wípé kí o fi òun sílè, má bínú si. Tí ó jé onítìjú obìnrin, ó kàn fé dáwà ni kìí kú se wípé kò fé kí bí ó se wà pèlú rè. Onítìjú nílò ìdáwà láti leè mú padà àti láti se ohun tí ó tó. Àkódá àti ìmólára tí won gbodò se ni, má Sì í gbó tí ó bá s’àdéédé dáké tàbí tí ó dáwà.
2. Jé kí ó wà lórí owó rè: sáà jé kí ó wà lórí owó rè, wò ó bóyá o leè gba ìgbésí ayé rè. Ó dára tí o bá leè jé kí ó gbé fúnra rè, tí ó bá fé kí o bá òhun sòrò, fúnra rè ló máa wá dìmó o gbàgì. Nígbà míràn o ti se oríre tí ó bá bá e se àwon eré kan tí onítìjú máa ń se.
3. Má fi agbára báa jo sòrò : tí ó bá dáké má fi agbára báa jo sòrò onítìjú máa dásí òrò tí ó bá dùn sùgbón won se èyí nígbà tí ó bá wù wón se kìí se tí ìwo bá fé, báyìí, nígbà míràn tí o bá bèrè sí ní so àwon òrò tí ó dùn, má rò wípé kí ó máa dunnú sí ní gbogbo ìgbà tí inú rè bá dùn e jo ma sòrò yín lo sùgbón tí ó bá tún yí sí bí ó se máa ń wà, ó kàn máa rora rérìń ni tí ó sì máa díbó bí eni tí ó ńgbó, tí o bá kàn jé kí ó wà lórí owó rè ó máa n’ìfé re si tí o bá se èyí.
4. Má fi agbára mu kí ó n’ìfé afefeyèyè : onítìjú máa ń se afefeyèyè sùgbón nígbà tí ó bá wù wón ni, báyìí, ònà wo ni à ń gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin? Má fi agbára mu kí ó bá e lo sí òde ìròlé àti ohun afefe míràn tí ìwo kún fún. Sùgbón o leè bií Sé ó máa lo láti dáhùn wípé béèni tàbí béèkó , ìyàwó rè kò le dàbí re ní gbogbo ònà . Bòwò fún un lónà tí ó tó jáde pèlú àwon Òré re, ní tòótó, onítìjú obìnrin dára ju aláròyé obìnrin lo dáa dáa.
5. Fún un láyè díè :tí o bá leè fun ní yàrá òtò nínú ilé re, ònà kan gbòógi rè é tí o fi leè gbé pèlú onítìjú obìnrin. Ó máa ń n’ìfé ìpamó, má fura sí I, kò ní ohun tí ó ń fipamó fún o ó kàn máa ń gbádùn ibi tí ó dáké róró ni, báyìí, ó ye kí ó ti yé e yín ònà tí a le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin.
Ònà rè é láti gbé pèlú onítìjú obìnrin…..
Continue after the page break for English Version