Home / Art / Àṣà Oòduà / Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.

Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.

oni ti ilè-ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi tí òun àti olorì télè èyí tí a mò sí olorì Wuraola tí pínyà ní osú ògún tí a mò sí odù kejo odún 2017, nse ni ó dàbí baba ti rí olólùfé míràn.

Nse ni ó dàbí eni wípé egbo ìfé baba ti san nígbà tí won rí Tope Adesegun.

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. ADESOJI ADEDAPO

    a dupe, OK congrat in advance

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...