Home / Art / Àṣà Oòduà / Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.

Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.

Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.
Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè kìí se èjè rárá.
Oba Adeyeye Enitan Babatunde omo Ogunwusi ti jé kí ó di mímò wípé èkejì efun tí a mò sí osùn ni olorì tè mólè, kí àwon èèyàn dáké kóntan kòntan tí won n so kiri.
Gégé bí a ti mò wípé àwon ìgbésì kòòkan wà tí èèyàn yóò gbé kí obìnrin náà tó wolé, ètóyí ni won se fún Yèyélúwà tuntun ooo.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti