Home / Art / Àṣà Oòduà / Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.

Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.


Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè.
Àwòrán ibi tí ìyàwó ti n se àwon ètùtú tí ó ye, tí ó sì dá èjè kojá.
Àdúrà wa ni wípé: kí olorì tuntun bí obìnrin àbíró, Okùnrin àbíyé (Àse).
Ó ti se é se..

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. Ajayi Happiness

    Been a Queen is important to her generation but doing the neccesary things is importanter…
    #prophetess turn to a Queen

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...