Home / Art / Àṣà Oòduà / Òrò ìsítí gbó òréëwa?

Òrò ìsítí gbó òréëwa?

Òrò ìsítí gbó òréëwa?

-O féékú wàákú,
Ìwõ ò fèékú wàákú sugbon kini kan lèmi fë kio mø daju, Sé nigba tó o wásí ile-aye sé kii sepé àrà(Wonder) ku mó ë ninu. Àrà tóò gbéwá silé ayé tóò ló, tíò “manifest ninu aye rë tawön eniyan o ” benefit ninu rë, tóo bá kú ilé-ayé asán lo wá, Sugbon àrà tóò gbewa ile-aye tóo lóò bó se tó, tóò sohun gbogbo lásìkò bósetó, Osisé lásìkò tóyë kóo se, tóò lówó bósetó,(normal way..) O ra okò lasiko tóyë koo raa, O wö asõ tó bágbà mu, O n sàánú fawon tóyë kó o sàánú fun, Bó o bákú ayé oni gbàgbé rë!
Një o mö wipe irufë igbe aye tóo báfé gbe öwö ara rë ni waafi faa, Bó o bafë gbe igbe aye rada-rada lati öwó ara rë ni yoo ti wa, Bó o ba fë gbe igbe-aye to dara õwó ara rë ni waa fi fa.
-Yoruba ni öwó ara ëni lafi ntun wa ara ëni se.
Iru ile aye wo lo ngbe loni òréëwa yë ara rë wo! Se igbe aye to ngbe loni bi øløjø bade se igbe aye tio jë ari tokasi ni abi iru igbe aye wo?
. Yë ara rë wo!
Hunn… Kíèsi eleyi naa.
-Má wo (copy)ìsesi onísesi, Máwo àsà alásà Nitori oyinbo ni “What’s not yours is not yours! Mú àsà tìë, Gbogbo mofë maa sòyìnbó bi Wole soyinka o lee dabi wöle soyinka, Mofë maa sòrò bii buhar omo mussa O lee dabi buhar, Mofë maa körin bí Michael Jackson o lee dabi Michael Jackson örë wa, Èbùn tí eledua fun onikaluku òtòòtò ni, Waa ni Àsà tië òréëwa, lori Àsà tio niyan, “big lee lori ntori bio “big lee lori iwö naa wa di aköni Lorie, waa di professional lorië taye o si tibë mö wø naa.
Ekale o,
Aku isë ēni.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti