Mo kí gbogbo yín o! Ẹ kú òwúrọ̀! Ìkéde ẹ̀kọ́ ọ Yorùbá tí yío bẹ̀rẹ̀ ní ìparí oṣù yí ni mo ní kí nfi tó o yín l’étí o. Bí ẹ ti mọ̀ tẹ́lẹ̀ wípé mo ti ṣe àfihàn onírúurú àwòrán àti ẹ̀kọ ọ Yorùbá lóríi fáràn tèmi lórí i Fesibúùkù fún bí ọdún méjé sẹ́hìn. Mo lérò wípé ẹ gbádùn rẹ̀, àti wípé àwọn ìtàn àti ẹ̀kọ́ náà wúlò fúun yín. Tí ẹ bá wà ní ìlú Detroit tàbí agbègbè tó sún mọ́o, ẹ lè dara pọ̀ mọ́ wa ní ọjọ́ náà. Àbọ̀ mi olóyin rèe o. Kí a pàdé láyọ́. (Ẹ ranti mu ònkọ̀wé dani o)
I greet you all! Good morning! This is to announce the commencement of my Yoruba classes that will start this month end January. To those who have been following my posts on Yoruba culture, language and stories for over 7 years, this is an opportunity to come closer and learn how to communicate in Yoruba language among many other goodies. If you live in Detroit or around Detroit, please join us on Saturday January 28th, 2017. We welcome you with joy. See you there in peace. (Please don’t forget to bring writing materials) —