Ní ìsàlé ni àwòrán ayeye ìgbéyàwó omo Saraki tí ó n jé Olutosin Halima Saraki, omobìnrin Saraki, omo asojú ilé-ìgbìmò asòfin , Bukola Saraki tí won se ní ilé ìtura àti ìgbàlejò (Eko hotel and suites ) ìpínlé…
Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...
Eto igbeyawo laye…Oluwami fi le le pelu ase ni.